Tuesday, December 9, 2014

Ejo se ebi omo ni abi ti baba

father son Ejo se ebi omo ni abi ti baba

Baba kan wa obi omo kan kunrin kan osope omo ohun kogbodo losi puplic school nitori ko le gbo oyinbo dada baba yii ni alejo ni ojo kan osofun omo yii ko lobu omi wa baba unba ore re soro nigba ti omo bomi de oso fun baba wipe omi re oo baba sope gbe lemi lori be ni omo ba da omi le baba lori ejo ta lo jebiEjo se ebi omo ni abi ti baba

No comments:

Post a Comment