Monday, May 4, 2015

Odu Ofun Owonrin

Alàáfia Community!!, continuity  gave us bàbá Faniyi Osagbami, here I am writing another “ese ‘fa ” could baba translate some have interpreted? thank you very much.
ifa

Here goes ….”…

1.Ofun wonrin wonrin awo igun lodifa fun igun

Ti nraye laini ku Gunnugun kii ku lewe Kangere ma dagba ma darugbo kangere.

2. Ofun jinginni Adifa fun Orunmila o gunyan tan ko robe je Ire aje, ire gbogbo nwa mi bo wa o. Ofun jinginni

3. Kukute kukuru awo eba ona Adifa fun Orunmila oun esu odara jo nsowo po Odara dare temi fun mi Odara.

4. Ofun wonrin wonrin awo ile Orunmila lodifa fun Orunmila ti nbe ni rangun ota Koipe koijina kawa bani larusegun….”

No comments:

Post a Comment