Monday, November 17, 2014

Ona wo ni won maa ngba siku agbalagba ode?

ibeere Ona wo ni won maa ngba siku agbalagba ode?

Ni kete ti agba ode kan ba rewaleasa ni awon akegbe re ninu ode yoo mura lati wa sinpa fun un.Eyi ma n waye fun oku lati yo ese re kuro ni agboole ati laaarin awon olode yoku ti won jo nse ise ode.leyin eyi ni ijo orin pelu awejewemu yoo wa sese bere ni perehu.



Ona wo ni won maa ngba siku agbalagba ode?

No comments:

Post a Comment