Friday, December 19, 2014

Aalo apamo - Mayaki Ojo

Aalo apamo


Obi awe kan aje de oyo, baba kukuru de fila bentigo, kini nboba jeun ti kii mu sibi dani? Aguntan baba mi kan lailai, aguntan baba mi kan lailai, owoo ni nje kii je agbado. ( Ahon, oko, esin-sin, Obinrin) happy xmas ni gbogbo kaaro oojire.
alo apamo Aalo apamo Mayaki OjoAalo apamo - Mayaki Ojo

No comments:

Post a Comment