Hunmmmmmm, Ẹ ku ọsan o, e ku ataaro o, o ga o, anu opolopo obinrin si se mi lojo oni, nitori opolopo ninu won lo ti so aponle ara re nu niti tori eja #300 ati hi malt #100, tabi tori aso #1,500 won ni awon nse ayajo ololufe. Awon oponu ayirada nigba ti o si je pe opolopo ni ko mowe ti won ya olodo kale, e lo wo itumo valentine dada ki e mo itu mo re ni odoodun ni awon okunrin fi nba aye awon obinrin je sibesibe won o gbon ni. Nigbati kosi si iberu olohun lara gbogbo wa.
Sebi won ni iberu olohun ni iplese ogbon, e je ki gbogbo wa beru olohun. Ki awa naa le ni ayo okan, olomo kan wa po lo bisu ewura, e wa ni awon okunrin gidi kife olomo kan talo ma ri agbebo edie loja to ma kowo le, e je ka sora ki a ma tori ede ba ode je. Oro mi ko po, die to fun ologbon eniyan. Ire ooo
Nigeria's no 1 blog for latest Nigeria Property, Nigeria House,Private Property Nigeria, Real Estate Nigeria, Lagos Island nigeria, lekki lagos real estate, arable farming land nigeria, Land for sale, to let,for sale and for rent.
Wednesday, February 18, 2015
Anu opolopo obinrin si se mi lojo oni !
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment