Saturday, May 2, 2015

Moki gbogbowa wipe aku ewu osu titun ti o wọle de wẹrẹ waba waa !

Mogbaladura wipe ogun aṣeti koni je tiwa ninu osu na,eni na tuni ọjọ (ẹtì) ti wonpeni (friday)…olodumare koni je ki akoju ogun aṣeti nile aye emi ati iwọ…
ifa

Ẹni tikole tele,ẹniti wa ọmọ latibi,ẹni fe aṣerori lori adawole ẹ,ẹni todawọ ikan tofe aṣeyori lori ẹ ki olodumare fun gbogbo won ni okun ati agbara lati ṣeyori..ase

tori IFA kan so ninu odumimo ẹ bayi wipe….

Abẹde awo olokira difa fun olokira eyiti otifi owun gbogbo se owoo aṣeti (woni o karanle ẹbọ nikose,owa rúbọ tan owa di alase yori)..nje abẹde o de oo awo olokira ORUNMILA jọwọ maki olokira o ṣe owo aṣeti…

Njẹ́ abẹde o de oo awo olokira ORUNMILA jọwọ majeki awa ọmọ e kose owoo aṣeti…

Ase…


~Ramon Nojim

No comments:

Post a Comment