Tuesday, November 11, 2014

Ebami dasi oro yi !!!

Awon okunrin kan wa,nigba

tiwon ba un nife Obinrin

lowo,won ama se i love,i love

u,titi ti obinrin na ma fi de ara

si fun won.tiwon bawa ri wipe

awon bani ajosepo tan,ti oyun

de,won a ba yowo wipe awon

ko ni awon ni oyun.titi osu

mesan,won dasi obinrin

na.won pati sepe kan,tititi omo

na fi dagba,tio fini ise gidi

lowo.

Nigba yen ni IRU Okunrin bee a

sese wa Obinrin ye kan,awa

ma be wipe kio mabinu.wipe

igba aimo ni.wipe kio dariji

oun.

Ibere mi wa ni………? Tio baje

iwo ni obinrin na,kini wase fun

iru okunrin yen?
ibeere Ebami dasi oro yi,



Ebami dasi oro yi !!!

No comments:

Post a Comment