Thursday, December 25, 2014

IFA University Quiz for the day: Abọru boye ẹyin Awo.

Could you identify what these 2 items are? Where are they found? Describe some of the things these items could be used for in Iṣẹṣe?
ifa ifa1

Kíni à nwò nínú àwọn àwòrán méjì yìí? Kínni wọ́n? Àti wípé níbo lati lè rí wọn?

Ṣe àpèjúwe àwọn ìwúlo wọn nínú Ìṣẹ̀ṣe?IFA University Quiz for the day: Abọru boye ẹyin Awo.

No comments:

Post a Comment